Policy:Universal Code of Conduct/yo: Difference between revisions

From Wikimedia Foundation Governance Wiki
Content deleted Content added
Imported translation using page migration
Imported translation using page migration
Line 73: Line 73:
* '''È̩gbin tàbí Ìwọ̀sí:''' Ara èyí ni pípení lórúkọ kórúkọ, àbòsí, àti fífi èèbú ara búni. È̩gbin tàbí ìwọ̀sí ni bíbúni ní pasẹ̀ bí ẹni nà ṣe n ronú, bí o ṣe rí, ẹ̀yà àti ìran tí ó jẹ́, irúfẹ́ ẹ̀sìn tí ó n sìn, bí àṣà àti iṣẹ́ rẹ̀ ṣe rí, ìṣe ìbálòpọ̀ rẹ̀, yálà akọ ni tàbí abo, ọjọ́ orí rẹ̀ ni, ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ ni tàbí àwọn nkan mííràn. Ní ìgbà mííràn, yí yẹ̀yẹ́ ẹni, ìfini rẹ́rìn tàbí ìfajúro síni léra léra sí ẹlòmíràn lè túmọ̀ sí ìwọ̀sí tàbí ẹ̀gbin l'ápàapọ̀, bí ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti lẹ̀ ṣe àìléwu.
* '''È̩gbin tàbí Ìwọ̀sí:''' Ara èyí ni pípení lórúkọ kórúkọ, àbòsí, àti fífi èèbú ara búni. È̩gbin tàbí ìwọ̀sí ni bíbúni ní pasẹ̀ bí ẹni nà ṣe n ronú, bí o ṣe rí, ẹ̀yà àti ìran tí ó jẹ́, irúfẹ́ ẹ̀sìn tí ó n sìn, bí àṣà àti iṣẹ́ rẹ̀ ṣe rí, ìṣe ìbálòpọ̀ rẹ̀, yálà akọ ni tàbí abo, ọjọ́ orí rẹ̀ ni, ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ ni tàbí àwọn nkan mííràn. Ní ìgbà mííràn, yí yẹ̀yẹ́ ẹni, ìfini rẹ́rìn tàbí ìfajúro síni léra léra sí ẹlòmíràn lè túmọ̀ sí ìwọ̀sí tàbí ẹ̀gbin l'ápàapọ̀, bí ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti lẹ̀ ṣe àìléwu.
* '''Ìyọlẹ́nu ìbáṣepọ̀:''' Ìfàmọ́ra fún ìbáṣepọ̀ sí àwọn ènìyàn tí o mọ̀ pé wọ̀n fẹ́, tàbí sí àwọn ènìyàn tí ó yẹ kí o mọ̀ pé kò tọ̀ nà, tàbí ní àwọn ipò tí kò ṣéé ṣe làti bèèrè fún ìgbàláyè wọn.
* '''Ìyọlẹ́nu ìbáṣepọ̀:''' Ìfàmọ́ra fún ìbáṣepọ̀ sí àwọn ènìyàn tí o mọ̀ pé wọ̀n fẹ́, tàbí sí àwọn ènìyàn tí ó yẹ kí o mọ̀ pé kò tọ̀ nà, tàbí ní àwọn ipò tí kò ṣéé ṣe làti bèèrè fún ìgbàláyè wọn.
* '''Ìhàlẹ̀:''' Ìhàlẹ̀ ìwà-ipá mọ́ni ní ìpamọ́ tàbí ní gbangba, ìdójútì àìtọ́, ìbani lórúkọ jẹ́ àìtọ̀, tàbí dídábàá làti p'ènìyàn l'ẹ́jọ́ nítorí kí o lè borí iyàn tàbí fi t'ipá jẹ́ kí ènìyàn ṣe ohun tí o fẹ́.
* <span lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">'''Threats:''' Explicitly or implicitly suggesting the possibility of physical violence, unfair embarrassment, unfair and unjustified reputational harm, or intimidation by suggesting gratuitous legal action to win an argument or force someone to behave the way you want.</span>
* <span lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">'''Encouraging harm to others:''' This includes encouraging someone else to commit self-harm or suicide as well as encouraging someone to conduct violent attacks on a third party.</span>
* <span lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">'''Encouraging harm to others:''' This includes encouraging someone else to commit self-harm or suicide as well as encouraging someone to conduct violent attacks on a third party.</span>
* <span lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">'''Disclosure of personal data (Doxing):''' sharing other contributors' private information, such as name, place of employment, physical or email address without their explicit consent either on the Wikimedia projects or elsewhere, or sharing information concerning their Wikimedia activity outside the projects.</span>
* <span lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">'''Disclosure of personal data (Doxing):''' sharing other contributors' private information, such as name, place of employment, physical or email address without their explicit consent either on the Wikimedia projects or elsewhere, or sharing information concerning their Wikimedia activity outside the projects.</span>

Revision as of 07:12, 21 March 2023

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí

Ìdí tí afi ní Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí

Agbàgbó nínu ríró agbára fún gbogbo ènìyàn tí ó n kópa nínú àwọn iṣẹ́ àti àwọn àyè wikimedia, láti lè dé bi ìran wa fún dídá irú ayé tí gbogbo ènìyàn lè pín nínu àwọn àkópọ̀ ìmọ̀ àwa ọmọ aráyé. Agbàgbó wípé àwọn olùkópa àjọṣepọ̀ wa yìí gbọdọ̀ jẹ́ onírúurú ènìyàn, àjọṣepọ̀ yìí sì gbọdọ̀ fani mọ́'ra níwọ̀n bí óti ṣeése. Afẹ́ kí àwọn ará àjọṣepọ̀ yìí máa wà ní dídára, pẹ̀lú ààbò t'ó pé'ye àti àyíká t'óní ìlera fún ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ darapọ̀ mọ́ wọn. A pinu láti ríi dájú pé ó wà báyìí, nípa fí'faramọ́ Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yìí àti ìmúdójúìwọ̀n ní gbà tí ó bá tọ́. Pẹ̀lúpẹ̀lú, afẹ́ dáàbò bo àwọn iṣẹ́ Wikimedia kúrò lọ́wọ́ àwọn tí wọ́n bàájẹ́ tàbí díilọ́wọ́.

Ní ìbámu pẹ̀lú àfojúsùn Wikimedia, gbogbo ẹni tí o bá ti ń kópa nínú iṣẹ́ Wikimedia yóò:

  • sapá láti ṣ'ẹ̀dá irú ayé tí gbogbo ènìyàn lè pín nínu àwọn àkópọ̀ ìmọ̀ àwa ọmọ aráyé
  • kopa nínú awujo àgbáyé tí yíò jìnà sí ẹ̀tanú àti ìkóríra, pẹ̀lú
  • sapá láti ríi dájú pé gbogbo àwọn iṣẹ́ Wikimedia pé dé ojú ìwọ̀n, ósì ṣeé jẹ́rìsí.

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (UCoC) yìí ṣe àlàpín sí àwọn ìwà tí ó tọ̀nà àti àwọn ìwà tí kò bójú mu. Òfin yí de gbogbo ẹnikẹ́ni tí ó bá ti ní nkan ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ àti àyeè àjọṣepọ̀ Wikimedia, yálà lórí ayélujára ni tabí ní ojúkojú. Òfin yí ta bá àwọn akópa titun tàbí àwọn tí wọ́n ti n kópa tipẹ́, àwọn alábòjútó àwọn iṣẹ́ Wikimedia, àwọn olùṣẹ̀tò àpẹ́jọ, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ onígbọ̀wọ́ àwọn ilé-iṣẹ́ Wikimedia, àwọn òṣìṣẹ́, àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation. Òfin yí ta bá àtèlé yìí:

  • ìbáṣepọ̀ àwùjọ ìkọ̀kọ̀, ti gbangba, tàbí èyí tí ó wà ní agbede méjì
  • àwọn ìjíròrò ti ìyapa àti àtìlẹ́yìn fún ìṣọ̀kan láàrin àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia
  • àwọn ọ̀rọ̀ lórí ìdàgbàsókè ìmọ̀-ẹ̀rọ̀ nà iṣẹ́
  • àwọn ọ̀rọ̀ tí ó dá lórí ṣíṣe àfikún àwọn àkòsílẹ̀
  • ìlànà bí àwọn ẹ̀ka aṣoju Wikimedia ṣe lè ṣojú wọn lọ́dọ̀ àwọn alábàáṣe wọn t'ìta

1 - Ìfihàn

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí ṣ'ètò ìpelẹ̀sẹ̀ iwà tí ó bójú mu fún àjọṣepọ̀ Wikimedia kárí àgbáyé. Àwọn ará Wikimedia ṣì le fikún àlàkalẹ̀ yìí láti ṣ'ẹ̀dá àlàkalẹ̀ tí yío j'ọmọ́ ṣakun àṣà, àti ìṣe tí ówà nílẹ̀, sùgbọ́n tí Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò sì gbodọ̀ jẹ́ ìpelẹ̀sẹ̀ fún.

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yìí de gbogbo àwọn ará Wikimedia ní bá'kàan láì yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀. Tí'tàpá sí Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yìí lè mú ìjìyà dání. Àwọn ìjìyà yìí lè wá láti ọwọ́ àwọn ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe Wikimedia tàbí/àti láti ọwọ́ Wikimedia Foundation, gẹ́gẹ́ bí olóun àwọn iṣẹ́ àjọṣepọ̀ yìí

2 - Ìwà tí ó bójú mu

Gbogbo àwọn ará Wikimedia, yálà wọ́n ti pẹ́ ni tàbí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ forúkọ sílẹ̀ ni, àwọn ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe Wikimedia, àwọn ẹ̀ka tàbí àwọn ìgbìmọ̀ onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation tàbí òṣìṣẹ́, ni won yóò ṣe ìdúró fún ìwà wọn.

Nínú gbogbo àwọn iṣẹ́, àyèè ati àpèjọ̀ Wikimedia, ìwà ìbọ̀wọ̀-fún, ìmẹ̀tọ́, ìbáṣepọ̀ tó lọ́ọ̀rìn, ìṣọ̀kan àti ìjẹ́ aṣojú rere ni a ń retí lọ́wọ́ gbogbo àwọn olùkópa. Àwọn ìwà wọ̀nyí ni a gbọ́dọ̀ ma gbóòórùn lará àwọn oníṣẹ́ aláfikún àti olùkópa pátá nínú ìbáṣepọ̀ wọn láàríin ara wọn, láì yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀ nípa ọjọ́-orí, ìpèníjà ara, ìṣesí, ìrísí, orílẹ̀-èdè, ẹ̀sìn, ẹlẹ́yà-mẹ̀yà, ìdẹ́yẹsíni, ipò-ayé, mímọ̀rọ̀'sọ, ìbálòpọ̀ akọ àti abo, ìjákọ tàbí ìjábo, ìmọ̀ tàbí iṣẹ́ ayé. A ò sì ní yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀ nípa ìmọ̀ tàbí iṣẹ́ wọn nínú àjọṣepọ̀ Wikimedia.

2.1 - Ìbọ̀wọ̀ fún ara ẹni

A ní láti máa bọ̀wọ̀ fún ara wa gẹ́gẹ́ bí a ṣe fẹ́ kí wọ́n o bọ̀wọ̀ fún àwa náà ní àwọn àyíká Wikimedia, yálà lórí ẹ̀rọ ayélujára ni tàbí ní ojúkojú. Agbọ́dọ̀ maa bọ̀wọ̀ fún ẹlòmíràn.

Lará rẹ̀ tún ni:

  • Síṣe ìgbatẹnirò. Fara balẹ̀ gbọ́ ohun tí ẹnikẹ́ni nínú àwọn akẹgbẹ́ rẹ tí wọ́n jẹ́ onise Wikimedia ba fẹ́ sọ fún ọ. Gbaradì láti lo ìmọ̀ àti òyé rẹ lórí ohun tí o ti gbọ́ gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ Wikimedia.
  • Jẹ́ kí ọkàn rẹ ó mọ́, kí o sì sọ̀rọ̀ pẹ̀lú àròjinlẹ̀; Àfíkun rẹ gbọdọ̀ ṣe àtúnṣe bá ìsẹ́ tí ò nfikún. Fèsì sí ọ̀rọ̀ pẹ́lú ẹ̀mí kan. Bí o bá ní ìyapa èrò lórí ọ̀rọ̀ kan, gbé ọ̀rọ̀ náà kalẹ̀ pẹ̀lú àròjinlẹ̀. Gbogbo ará Wikimedia gbọdọ̀ ṣe àtúnṣe pẹ̀lú ọkàn mímọ́, tí kòbá sí ẹ̀rí pé ẹnìkejì jẹ́ oníbàjẹ́. Pẹ̀lúpẹ̀lú, o kòsì gbọdọ̀ s'ọ̀rọ̀ ìpalára sí oníbàjẹ́ tí o bábá wọn pàdé.
  • Bọ̀wọ̀ fún bí àwọn oníṣẹ́ bá ṣe pe orúkọ tàbí ṣàpèjúwe ara wọn. Àwọn ènìyàn lè lo onírúurú ìlànà láti ṣàpèjúwe ara wọn. Gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ ìbọ̀wọ̀ fún, lo ìlànà tí wọ́n bá fi pe ara won gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe lòó, nígbà tí o bá ń bá wọn sọ̀rọ̀ tàbí sọ̀rọ̀ nípa wọn, níwọ̀nbí ótiṣééṣe . Bí àpeere:
    • Àwọn ẹgbẹ́ ẹ̀yà kan lè fi orúkọ pàtàkì láti ṣe àpèjúwè ara wọn, dípò orúkọ tí àwùjọ mọ̀ wọ́n sí;
    • Àwọn ènìyàn kan lè lo àwon lẹ́tà, ohùn, tàbí ọ̀rọ̀ láti inú èdè won tí yòò ṣàjòjì sí ìwọ;
    • Àwọn ènìyàn tí nṣe ìbálòpọ̀ akọ àti abo ọ̀tọ̀, léè lo arọ́pò orúkọ tó yàtọ̀;
    • Àwọn ènìyàn tí wọ́n ní ìpèníjà ara kan tàbí òmíràn lè lo ohunkóhun láti fi jùwé ara wọn.
  • Ní àwọn ìpàdé ojúkojú, a ó gbìyànjú láti fa gbogbo ènìyàn mọ́ra, a ó sì ri wípé a bu ọ̀wọ̀ fún àwọn àyòò, àlàà, ohun ìpalára, àṣà, àti ìbéèrè oníkálukú.

2.2 - Ìwà-Ẹ̀tọ́, ìfọwọ́sowọ́pọ̀, ìṣọ̀kan àti ìjẹ́ asojú rere

Àwọn ìwà tí à nretí nì yíí:

  • Ìwà-È̩tọ́ ni mímọ ìwà, ọ̀rọ̀ àti ìṣesí tí ó tọ́ láàrin àwùjọ, pẹ̀lúpẹ̀lú àlejò.
  • Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ni ìkúnra-ẹni lápá tàbí àṣà ìranra-ẹni lọ́wọ́ tí ó yẹ láàrin àwọn alábàṣisẹ́pọ̀
  • Ìṣọ̀kan àti ìjẹ́ aṣojú rere ni mímú ojúsẹ láti rí dájú wípé gbogbo àwọn isẹ́ Wikimedìà n so èso, wọ́n dùn ún ṣe, wọ́n sì n jẹ́ àwùjọ ààbò, àti fún ìdàgbàsókè àfojúsìn àjọṣepọ̀ Wikimedia

Lará rẹ̀ náà tún ni:

  • Jẹ́ Atọ́nà àti Olùkọ́: Ran àwọn ẹni tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ dara pọ̀ lọ́wọ́ láti mọ̀nà àti láti ní ìmọ̀ kíkún lórí bí Wikimedia ṣe ń ṣiṣẹ́.
  • Fi ìṣòkan hàn. Máa ran àwọn oníṣẹ́ bíi tìrẹ lọ́wọ́ nígbà kúùgbà tí wọ́n bá nílò ìrànwọ́ rẹ, kí o sì sọ̀rọ̀-sókè fún wọn bí wọ́n bá n fi ẹ̀gbin kan wọ́n tí ó lòdì, gẹ́gẹ́ bí Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí.
  • Ṣè'fihàn, kí o sì dúpẹ́ fún iṣẹ́ tí àwọn olùfarajìn nṣe: Dúpẹ́ fún ìrànwọ́ àti isẹ́ wọn. Ṣè'rántí akitiyan wọn ní àwọn ibi tí ó ti yẹ.

3 - Ìwà tí kò bójú mu

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yìí yóò ràn gbogbo àwọn ará wikimedia lọ́wọ́ láti lè ṣe àdáyanrí àwọn ipò ìwà tí kò tọ́. Àwọn ìwà wọ̀nyí ni a lè pè ní ìwà tí kò tọ́ láàrín àwùjọ àjọṣepọ̀ Wikimedia.

3.1 - Ìyọlẹ́nu

Èyí jẹ́ àwọn ìwà tí ó lè fa ìjayà tàbí ìbínú láti ọ̀dọ̀ ẹlòmíìràn. A lè wo ìwà kan gẹ́gẹ́ bí ìwà ìyọlẹ́nu nígbà tí ó bá ti kọjá ohun tí ènìyàn lè gbà mọ́ra ní àwùjọ àgbáyé ti onírúurú. Ìwà Ìyọlẹ́nu má n ṣábà wáyé ní pasè ẹ̀dùn ọkàn, pàápàá sí àwọn tí ó bá wà ní ìkoríta ìpalára, nípa kíkàn sí ibi-isẹ́, tàbí ọ̀rẹ́ àti ẹbí, láti fa ìdàmú tàbí ìdójútì. Ní ìgbà míràn, àwọn ìwà tí kò ní ewu ní ìsẹ̀lẹ̀ kan, lè padà di ìwà ìyọlẹ́nu, tí óbá wá nsẹlẹ̀ léra léra. Ara àwọn ìwà ìyọlẹ́nu ni:

  • È̩gbin tàbí Ìwọ̀sí: Ara èyí ni pípení lórúkọ kórúkọ, àbòsí, àti fífi èèbú ara búni. È̩gbin tàbí ìwọ̀sí ni bíbúni ní pasẹ̀ bí ẹni nà ṣe n ronú, bí o ṣe rí, ẹ̀yà àti ìran tí ó jẹ́, irúfẹ́ ẹ̀sìn tí ó n sìn, bí àṣà àti iṣẹ́ rẹ̀ ṣe rí, ìṣe ìbálòpọ̀ rẹ̀, yálà akọ ni tàbí abo, ọjọ́ orí rẹ̀ ni, ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ ni tàbí àwọn nkan mííràn. Ní ìgbà mííràn, yí yẹ̀yẹ́ ẹni, ìfini rẹ́rìn tàbí ìfajúro síni léra léra sí ẹlòmíràn lè túmọ̀ sí ìwọ̀sí tàbí ẹ̀gbin l'ápàapọ̀, bí ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti lẹ̀ ṣe àìléwu.
  • Ìyọlẹ́nu ìbáṣepọ̀: Ìfàmọ́ra fún ìbáṣepọ̀ sí àwọn ènìyàn tí o mọ̀ pé wọ̀n fẹ́, tàbí sí àwọn ènìyàn tí ó yẹ kí o mọ̀ pé kò tọ̀ nà, tàbí ní àwọn ipò tí kò ṣéé ṣe làti bèèrè fún ìgbàláyè wọn.
  • Ìhàlẹ̀: Ìhàlẹ̀ ìwà-ipá mọ́ni ní ìpamọ́ tàbí ní gbangba, ìdójútì àìtọ́, ìbani lórúkọ jẹ́ àìtọ̀, tàbí dídábàá làti p'ènìyàn l'ẹ́jọ́ nítorí kí o lè borí iyàn tàbí fi t'ipá jẹ́ kí ènìyàn ṣe ohun tí o fẹ́.
  • Encouraging harm to others: This includes encouraging someone else to commit self-harm or suicide as well as encouraging someone to conduct violent attacks on a third party.
  • Disclosure of personal data (Doxing): sharing other contributors' private information, such as name, place of employment, physical or email address without their explicit consent either on the Wikimedia projects or elsewhere, or sharing information concerning their Wikimedia activity outside the projects.
  • Hounding: following a person across the project(s) and repeatedly critiquing their work mainly with the intent to upset or discourage them. If problems are continuing after efforts to communicate and educate, communities may need to address them through established community processes.
  • Trolling: Deliberately disrupting conversations or posting in bad-faith to intentionally provoke.

3.2 – Abuse of power, privilege, or influence

Abuse occurs when someone in a real or perceived position of power, privilege, or influence engages in disrespectful, cruel, and/or violent behaviour towards other people. In Wikimedia environments, it may take the form of verbal or psychological abuse and may overlap with harassment.

  • Abuse of office by functionaries, officials and staff: use of authority, knowledge, or resources at the disposal of designated functionaries, as well as officials and staff of the Wikimedia Foundation or Wikimedia affiliates, to intimidate or threaten others.
  • Abuse of seniority and connections: Using one's position and reputation to intimidate others. We expect people with significant experience and connections in the movement to behave with special care because hostile comments from them may carry an unintended backlash. People with community authority have a particular privilege to be viewed as reliable and should not abuse this to attack others who disagree with them.
  • Psychological manipulation: Maliciously causing someone to doubt their own perceptions, senses, or understanding with the objective to win an argument or force someone to behave the way you want.

3.3 – Content vandalism and abuse of the projects

Deliberately introducing biased, false, inaccurate or inappropriate content, or hindering, impeding or otherwise hampering the creation (and/or maintenance) of content. This includes but is not limited to:

  • The repeated arbitrary or unmotivated removal of any content without appropriate discussion or providing explanation
  • Systematically manipulating content to favour specific interpretations of facts or points of view (also by means of unfaithful or deliberately false rendering of sources and altering the correct way of composing editorial content)
  • Hate speech in any form, or discriminatory language aimed at vilifying, humiliating, inciting hatred against individuals or groups on the basis of who they are or their personal beliefs
  • The use of symbols, images, categories, tags or other kinds of content that are intimidating or harmful to others outside of the context of encyclopedic, informational use. This includes imposing schemes on content intended to marginalize or ostracize.